WAEC Yoruba Language Questions and Answers 2022/2023 | Theory and Objective

WAEC Yoruba questions and answers. Question 2022 from the WAEC Yoruba exam is now accessible. The West African Examination Council (WAEC) will write the SSCE Yoruba Language paper.

WAEC Yoruba

The following o’level Waec yoruba questions 2022 are for Paper 1 & 2: Objective & Essay, which will begin at 9:30 a.m. and end at 12:30 p.m. As a result, the examination will take three hours.

WAEC Yoruba answers loading…

SEE ALSO:

New WAEC Timetable

WAEC Foods and Nutrition Practical Questions and Answers

WAEC Marketing Questions and Answers Theory and Objectives

WAEC Igbo Questions and answers

WAEC Hausa language questions and answers

WAEC free Yoruba Language questions and answers

In this post, I will give you free access to WASSCE Yoruba free answers for 2022 examination.

Read all introductions on the question paper carefully before you start answering.

Also,send us a message on WhatsApp to get more.

Yoruba questions

Yoruba

Yoruba questions

Yoruba

WAEC Yoruba Objective Questions & Answers 2022

1-10: CBDCBCCDEB

11-20: DEEDADCEBD

21-30: CCCCBEECAB

31-40: AEACBACAEC

41-50: ECABDDBBEB

51-60: BEADEBDCDD

2022 WASSCE Essay questions and answers

1d.

Èso ori ọpẹ ni a npe ni ẹyin. Oriṣiriṣi ohun iyebiye li a nri lati ara ẹyin. Lati inu ara ẹran ẹyin li a ti nyọ epo pupa; lẹhin ti a ba si ti yọ epo ara rẹ kuro tan, fukufuku ti o ku ni iha ti a fi nda ina ran. Gẹdẹgẹdẹ ti o ku ninu ẹkù lẹhin ti a ba fọ epo tan ni oguṣọ ti a fin tan ina. Nigbati a ba se epo jinna, ti a si re ogeere ori rẹ, kẹtẹpẹ isalẹ rẹ ni ikẹtẹ ti a fi njẹ iṣu.
Koro ti a o ba ninu ẹyin lẹhin ti a ba bo ẹran ara rẹ kuro li a npe ni ekurọ. Korofo ekurọ a maa le koko gẹgẹ bi eepo agbọn. On li a npe ni eesan. Ti a ba pa ekurọ, ti a si fo eesan rẹ, eso ti a o ba ninu rẹ ni ekurọ gaan. Ati eesan ti a fọ wẹwẹ, ati ọmọ inu ekurọ, ko si eyiti ko wulo ninu wọn. Eesan ekurọ wa fun ina dida; o jo ina ju epo lọ; on li awọn alagbẹdẹ fi nfin ina ewiri.
Nigbamiran, a maa jẹ ekurọ lasan, awọn ẹlomiran a si maa din i, nwọn a maa fi jẹ ẹwa yiyan. Ṣugbọn ohun pataki ti ekurọ wa fun laarin awọn Yoruba ni pe ara rẹ ni a ti nyọ adi ẹyan ti awọn obinrin fi ndi irun, ti a si fi nṣe egboogi nigbamiran. Ara ekurọ yi kannaa ni a ti nyọ eroja ti a fi nṣe ọṣẹ dudu.
Ni aiye Oyinbo yi, ohun iyebiye ni epo ara ẹyin ati ekurọ inu rẹ jẹ fun awọn agbẹ, nitoripe awọn oyinbo oniṣowo a maa ra wọn, owo geregere ni nwon si nsan lori wọn.
Lara igi ọpẹ ni a ti nda ẹmu. Ṣugbọn ni akoko ti a ba nda ẹmu l’ara ọpẹ, a ko le ri ẹyin kọ l’ori rẹ. Opọlọpọ igi ọpẹ ni a nda si fun ati maa da ẹmu l’ori wọn. Ogọọrọ si ni awọn ti nwọn fi ẹmu dida, ẹmu riru ati ẹmu tita ṣe iṣe ṣe. Owo ẹmu ti di owo pataki ni awọn ilu nla ilẹ Yoruba nisisiyi, owo kekere kọ li o nti idi owo wọnyi wa, paapaa ni akoko ogun ti o kọja yi, ti ọti oyinbo wọn bi oju; ti dudu ti funfun l’o nmu ẹmu; eyi ti ko mu ẹmu nmu ọgọrọ. Awọn ti o l’aiya ngbidanwo, nwọn nfi ẹmu ṣe ọti ti nwọn npe ni ‘Oyinbo gọ.’ Ṣugbọn eyi lodi si ofin, nitoripe ọti yi ko dara fun ara; ẹniti ọwọ ijọba ba si tẹ nidi ọti yi, nwọn a jẹ ẹ ni iya gidigidi.
A ko le ṣẹṣẹ maa sọ pe gbogbo ara ni igi ọpẹ fi wulo. Igi rẹ afara; ewe ori rẹ, mariwo, imọ ọwọ̀, okun, agbọ̀n, eso ori rẹ, epo, ikẹtẹ, iha, oguṣọ, eesan, ekurọ, adi, ọṣẹ; oje ara rẹ, ẹmu. Igi ọpẹ dara l’oju, o wulo, o si l’owo l’ori. Ko si igi ti o dabi igi ọpẹ.

1e.

ISELE LAABI KAN TO SOJU MI

Ijanba ina kan ti o sele loju mi waye ni ojo kerinla osu keji odun 2013. O wa ye ninu soobu kan ni alaguntan, iyana ipaja. Soobu yi ko jina siibi ti ise mi wa. Soobu naa wa ni abe ile alaja meta ti o do ju ko ilepo mobili ni alaguntan.

Ninu soobu yi foomu ibusun niwon nta nibe ti won npe ni matiraasi. Oja yii si kun inu soobu yi biba. Gbogbo ita soobu naa ni foomu naa wa. Omoyibo kan ni oni soobu naa. Ni ojo ti isele laabi yi sele, nkan kekere ni o fa sababi. Eeyan kan wa ti o sese gba soobu tire legbe soobu oni foomu yi. O wa pe awon ajorin, weda lati wa ba a jo awon irin kan po ninu soobu naa. Soobu tuntun yi ati ti onifoomu si fegbe kan arawon ni.

Bi ogbeni weda se n ba ise jorin jorin re lo, ina weda n se yo, o nta jade bo tin sise naa. Lai mo wipe ina na ti ta ba okan lara awon foomu to wa legbe soobu naa. Ko se ni to tete kofiri nkankan. Nigba to maa fi to ogun iseju opolopo foomu ti lana ninu soobu lohun. Eefin ti bole. Ina tinso laulau la be dekini. Eefin nlanla ti bo gbogbo ile alaja meta naa. Awon eniyan tin sa kijokijo. Ariwo tin so.

Ese ero tipe jo, awon eniyan ti n gbiyanju orisirisi nkan lati pa ina na. olomi ti nda omi, olose tin da ose si nu ina na, awon to ni agolo iyefun panapana gbe ti won jade won tee sinu ina yi sugbon kaka ko san lara iya aje ina yi, pipele lo n pele sii. Laipe ina na ti ran awon soobu to wa legbe ibe.

Won ti pe awon panapana, sugbon ki won to o de gbogbo foomu ti jona tan. Gbogbo nkan to wa ninu soobu keji naa ti jona tan ki won to o de. Ina ti fe ma ran lo soke ki awon panapana to o de.Nigba tii won de, won se gudugudu meje pelu yaya mefa won si ri ina naa pa.

Enito ni soobu kosi nibe nigba tii oran yi sele, won lo pee wa ni, nigba ti o yo lookan ti o ri ina na, nse ni o bu sigbe peregede, o ka wo le ri, o fi di jale. Awon eniyan roomu, won paro wa fun.

Nigba tii wahala ina yii maa fi bere ogbeni weda ti pari ise, ko mo nkankan to sele, nigbatii won lo pe de, to yo lookan, to ri ina to nbinu laulau, baba yi daku lo gborangandan ni o. Won ro mi lee lori kotoo ji ni o.
Adura mi ni wi pe oluwa ko ni je kari iru isele laabi yi mo. Imoran mi fun awon onise owo paa paa julo awon ti o nlo ina ninu won, ni wi pe ki won tun bo maa kiyesi sara. A o ni ri ja ina o. ki awon oni soobu maa ri wi pe won pa gbogbo ina soobu ki won to o ma lo sile.

Question 2a

Lati ṣe alaye alaye naa daradara, o ṣe pataki lati mọ bi awọn apejuwe pupọ ati alaye bi o ti ṣee nipa ohun ti o ri. Ninu aye igbalode, foonu jẹ ohun elo pataki ti o ṣe iranlọwọ lati tọju ifọwọkan pẹlu aye ita

2b

Foniimu lo fi iyato han laarin itumo oro ka si ekeji ati iyato han laarin iro ede kan si ekeji. “/ /” ni akanmo ti a fi n se adato

(7)
(i) ikini/ibowo: A ri Adio ati Abeni ti won fi ikunle ati idobale ki oloye oladejo
DM for the rest

(4a)

Oro asopo ni awon oro ti a n lo lati fi so oro tabi apola tabi gbolohun meji abi ju beelo po ninu gbolohun

Yoruba

(4b)

(i) Ati
(ii) Pelu
(iii) sugbon
(iv) oun
(v) Ambosi

WAEC Yoruba 5

Yoruba 6

Yoruba 6

 

WAEC WYoruba Past questions and answers

2020 answers

SECTION A: Aroko

1. (a) Ìdíje kan tí ó wáyé ni ilé-ẹ̀kọ́ mi.
(b) Ọ̀rẹ́ mi tí mo fẹ́ràn jù lọ.
(c) Ìsàlẹ̀ orọ̀ ní ẹ̀gbin.
(d) Ẹ̀sìn ti dòwò lórílẹ̀ èdè yìí.
(e) Ko lẹ́tà sí ọ̀rẹ́ ri tí ó wà ní ilẹ̀ òkèèèrè kí o sàlàyé  akitiyan ìjoba lórí iná ẹ̀létíírìkì ní orílẹ̀-èdè rii.

2. sàlàyé ìhun ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wúnrẹ̀n wọ̀nyí kí o sì fi àppeere méjì méjì gbe ìdáhùn rẹ̀ lẹ́sẹ̀:
(a) àrànmọ́wájú;
(b) àrànmẹ́yìn:
(c) àrànmọ́ aláìfòró.

3. (a) Kí ni fáwẹ̀lì?
(b) Ṣe àpèjúwe ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fáwẹ̀lì wọ̀nyí:
[i], [Ԑ], [a], [o], [ũ], [ͻ̃].

4. (a) Da´ru´ku i`s?`ri´ ?`r?` ti a fala` si´ ni´nu´ ?`k?`?`kan a`w?n gbo´lo´hu`n w?`nyi´:
(i) E?ku`n pa eran.(ii) B?´la´ ri`n de´ ile´.
(ii) W?´n gba owo´ Ade´??la´.
(iii) O´ pupa fo`o`.
(iv) Aja´ gbe´ eegun.
(v) Mo fo aoo.
(b) Lo ?`k?`?`kan ?`r?` ti a fa`la` si´ ni ab?` (a) g?´g?´ bi´ ori´ ni´nu´ gbo´lo´hu`n a`ki´ye`si´ ala´t?num?´.

SECTION B

6. Nínú ìtàn “Ìjàpá àti àwọn Ẹranko” ète wo ni Ìjàpá pa àti pé báwo ni àṣírí rẹ̀ ṣe tú?

7. Ṣalàyé ohun tí ifá so nipa Ògún.

8. se àlàyé kikún nipa bi Ọ̀jẹ́làdé ti o di ọ̀nì ṣe di ènìyàn padà.

9. Ṣàlàyé lẹ́kùnrẹ́rẹ́ ohun tí ó ṣokùnfà kíkó jáde ìyá Ọlánikẹ̀ẹ́ nílé ọkọ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì.

10. sàlàyé ìhùwàsí Ahun gẹ́gẹ́ bi akéwì ṣe fì yé wa nínú ewì náà.

11. sàlàyé bí Àbẹ̀ó ṣe ba ayé Àńwòó jẹ́.

SECTION C: ASA

12. Dárúku oríṣì oúnje mẹ́fà tí a ń fi erèé/ẹ̀wà se kí o sì sàlàyé bí a tì ń se méjì nínú won.

13. Dárúko mẹ́fà nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀de kí o sì sàlàyé sókí sókí lórí ọ̀kọ̀ọ̀kan.

Note: This is not a WAEC expo website. The questions above are likely/past questions and answers to enable you practice and score good grades.

How to pass WAEC Yoruba examination

Now that you have seen how Yoruba for 2022 will look like, it is important you also get the necessary tips you need to observe in order to pass your exam very well.

1. Trust yourself

Self-confidence is another factor that affects the performance of a candidate. Promise to do everything by yourself and all will come out very easy.

It is well known that many students cancel the right answers only to copy the wrong ones because they do not have confidence in themselves. You’re a miracle for the day, study and pray hard.

2. Start Early Study

In your life as a student, studying is very important. WAEC is a very simple exam for the duration of the study. To study is one thing and to study on time is something completely different.

Do not wait so long before you begin studying for the WAEC 2022 Yoruba examination. You really won’t be helped by late preparation. There will be time to review before exams when you begin studying early.

3. Utilize the WAEC Yoruba Syllabus 2022

It is extremely important to use the WAEC 2022 curriculum as it will help you to cover important topics. Without the Syllabus you will concentrate on unnecessary subjects not presented in examinations.

No need going to cover a whole textbook just to pass a particular subject. That would be stressful on your own side. The syllabus are important because all your questions will come from there.

Syllabus gives you area of concentration and also the list of textbooks which you will use to cover those topics.

Manage your time in the examination hall wisely

It is risky to remain in one question for more than the expected time. For objectives, you should be able to answer all your questions 15 minutes before the exam ends. Use the remaining time to dot your ‘I’s and cross your ‘T’s. In other words, use it to go through your work and make the necessary corrections.

For the essay part of the exam, ensure you do not exceed he proper time for each question. No matter how simple or hard a question would be, don’t dwell much on it.

To be able to manage your time properly, I recommend you go in with a wrist watch. Always allocate time to each question and try to finish it within that period.

Be timely to the examination venue

During the examinations, punctuality matters. Go early on to the examination site so the brain can do the job. When you rush into the examination hall you will be unstable and susceptible to so many mistakes.

Take the time before you begin to answer an examination question paper. WAEC Additional questions and answers on Yoruba Language.

If you have any questions and answers concerning the WAEC 2022, please let us know in the comment box.

Also read my article on how to pass any kind of exam.

If you have any question, please drop your comments below.

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *